Ilẹ Yoruba Ni Ilorin

Itan Yoruba
Itan Yoruba
13.7 هزار بار بازدید - 3 سال پیش - Laipẹ yí ni Sheik Abeeb
Laipẹ yí ni Sheik Abeeb ṣe wasi kan ni Ìlọrin pé Ilorin kiise Ilẹ̀ Yorùbá lèyí to tako ojulowo Ìtàn àti Ẹri.
Baba Àfọ̀njá mẹta lo jẹ Balẹ Ilorin tẹle rawọn, 1. Láderin 2. Pàsìn 3. Alùgbìn lehin àwọn mẹta ni Àfọ̀njá jẹ Balẹ láti orí balẹ ni Àfọ̀njá tí jẹ Kakanfo nítorí balẹ ìlú lọ ma ń jẹ Ààrẹ Ọna Kakanfo nigbana abẹ Aláàfin Ọ̀yọ́ lo si wa pelu Basorun Gaa lọ pa Balẹ Ìlọrin kejì Pàsín.
Aare Laji Abbas +2348023687432
3 سال پیش در تاریخ 1400/01/01 منتشر شده است.
13,781 بـار بازدید شده
... بیشتر