Oyigiyigi Olu Orun (Tungba Yoruba Praise Medley) Lyrics Video (with English Translation)

Noble Omoniyi
Noble Omoniyi
42.8 هزار بار بازدید - 3 سال پیش - This is the official Lyrics
This is the official Lyrics Video of Oyigiyigi Olu Orun by Noble Omoniyi.
lyrics:

Oyigiyigi Olu Orun
(Indestructible Rock, God of Heaven)
Atoba jaiye
(With You we have a fulfilled life)
Eleda oun gbogbo
(You, The Creator of all things)
Gbobo agbaiye iba m’oriki re
(If only the World could Understand who You really are)
Bawo ni’i iba ti dun to
(The World would be a much better place)


Oluwa mi mo dupe,
(Thank You my Lord)
Fun abo re Lori mi,
(For your protection over me)
Opo Egbe mi ti ku.
(A lot of people are dead)
Ti won ti file bora,
(Buried in the Ground)
Oluwa mi moyin o.
(My Lord I give you praise)
Pe mo wa Laaye
(That I am a Living being)

Oyigiyigi oh oh
(The Indestructible Rock )

Alagbawi Eda ah ah,
(Our Advocate)
Alakoso orun
(The co-ordinator of the heavens)

Eyin ma lo lo ogo julo.
(You are the glorious GOD)


Eyin le to be e
(You Deserve it)Eyin le to o
(Only you deserves it)Eyin le to lati gba ogo
(You deserve the glory)Eyin le to o Baba
(You deserve it father)

Oluwa ti s’oun nla teni kan kan o le se
(God has done a great thing that no one could do)
Eniyan lo ti pari sugbon Baba ti se o
(Men said it was finished but my Father has done it)
Nitorina mo yin o Ose Baba
(Therefore I praise you, thank you Father)

Chorus
Ose Baba ose Om (thank you Father thank you Son)

Agbanilagbatan o
(The Ultimate Deliverer)

O se Baba
(Thank you Father)

Baba, Iwo l’a o ma sin
(Father it is thee we shall serve)

Baba, Iwo l’a o ma bo
(Father it is thee we will worship)

Iwo to fe wa l’a o ma sin titi
(Oh Thou who love us we shall serve forever)

Mimo l’ogo ola re.
(Holy’s Thy glorious honor)


Kábíyèsí o, hòsánnà o
(Unquestionable Hossana)
Ẹ yin Jésù Kristì Ọba àìkú
(Praise Jesus Christ, The Living King)
Kabiyesi o, hosanna o
(Unquestionable Hossana)

Ẹ yin Jésù Kristì Ọba àìkú
(Praise Jesus Christ, The Living King)
Ẹ gbé E ga, Ẹ yin Jésù o
(Lift him High, Praise Jesus)
Ẹ yin Jésù Kristì Ọba àìkú
(Praise Jesus Christ, The Living King)
3 سال پیش در تاریخ 1400/10/17 منتشر شده است.
42,862 بـار بازدید شده
... بیشتر